Aanu – Sola Allyson

 

Intro

Aanu nbe ooo
Aanu wa /2x

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o

Aanu nbe fun oo, omo
Aanu wa
Aanu nbe nile alaanu
Aanu wa

Aanu nbe ooo
Aanu wa /2x

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o

Verse 1

Aanu
Mo mo olorun aanu /3x
Ise yi ni mo waa je
Bo ti wu ko ri aanu wa
Ileku aanu koi ti ti
Paragada losi si le

Omo maa bo
Omo maa bo
Omo maa bo waa
Imole a tan aanu si wa
Omo maa bo ooo

Chorus

Aanu nbe fun o omo ooo
Bo ti le wu ko ri aanu wa /2x

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o /2x

Verse 2

Asise
S’oti s’asise
Idamu s’oti ri’damu
Ibanuje
So ri’banuje
Ise yi ni mo waa je
Alanu ma lo nkanku
Iyipada re lo nbere
Ododo re kii ye
Boju wo’ke fi gbogbo re si le
Ko ya sa’re wa
Igbala a wa
Gba itusile
Isod’omo nbe

Chorus

Aanu nbe fun o omo ooo
Bo ti le wu ko ri aanu wa /2x

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o /2x

Verse 3

Irin kurin
Iwakiwa
Isekuse
Erokero
Ati’ru won ni

Ife osi
Ko s’enikan
Owa ife
O lo sise
Ati’ru won ni

Pansaga
Agbere
Iwa eeri
Ipaniyan
Ati’ru won ni

Chorus

Aanu nbe fun o omo ooo
Bo ti le wu ko ri aanu wa /2x

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o /2x

Outro

Aye si nbe
Ni le odo agutan
Ewa ogo re npe o pe maa bo
Wole wole
Wole ni si si yi
Ewa ogo re npe o pe maa bo

Ile aanu oluwa kii su
Ojo aanu oluwa kii da
Orun aanu oluwa ki’ma i wo
Aanu nbe fun o /2x

Top