Adura – Babatunmise

 

VERSE

Jiji moji lowuro
Orin ope mo muwa
Mo wole ni’waju re oo
Baba gb’ope mi

Lilo bibo mi baba
Mo file o lowo ooo
Maa je n rin lojo t’ebi n pono
Angeli mi maa shomi loo

Je ki n pade alaanu mi
Je ki idunnu ma gbenumi
Orin ope lenu mi

CHORUS

Adura ni mo gba oo
T’ogun aye fi wo
Adura ni mo gba oo
T’ono mi fila oo
Adura ni mo gba oo
T’aye mi fi dara
Ohun owo ole se
Adura lo le se

Emi o gboju mi Si
Ori oke won ni
Nibi ti iranlowo yio ati wa
Agbara ko, eniyan ko
Oba mi orun lo semi lore

Adura ti mo gba lojo si
she ohun loluwa fi dami si
Orun ti gbo, ase ti gun
Igbagbo mi so mi dotun

Igbagbo mi so mi dotun
Adura lopa kiristeni
Adura lagbara ti mo gboju le

Bi beru bamu oni gbagbo foya
Adura lo le se
Bi ogun Pharao ba gbeja lemi
Adura lo le se
B’araye bere pe olorun mida
Adura lo le se
Nigba riri je, nigba airije
Adura lo le se

Adura lo ma se…

Top