Alagbada Ina – Dr. Paul Enenche

 

 

CHORUS

Alagbada Ina
Alawotele oorun
Atofarati ooo
Eku ise ooo

Alagbada Ina
Alawotele oorun
Atofarati ooo
Adupe ooo

VERSE

Eku ise, Eku ise
Eku ise, Eku ise
Eku ise, Eku ise
Oluwa wa

Adupe, adupe
Adupe, adupe
Adupe, adupe
Olorun wa

Ijo fun Jesu
Jesu ni Baba

CHORUS

Alagbada Ina
Alawotele oorun
Atofarati ooo
Eku ise ooo

Alagbada Ina
Alawotele oorun
Atofarati ooo
Adupe ooo

BRIDGE

Eledumare, adupe
Eledumare, eku ise ooo
Eledumare, adupe
Eledumare, eku ise ooo

Download Lord, I Remain Your Baby by Dr. Paul Enenche

Eledumare, adupe
Oyigi, eku ise ooo
Atobajaye, adupe
Arugbo ojo, eku ise ooo
Alagbara nla, adupe
Atobiju, eku ise ooo
Eledumare, adupe
Atofarati, eku ise ooo
Oba mimo, adupe
Alagbara giga, eku ise ooo
Arugbo ojo, adupe
Erujeje, eku ise ooo
Eledumare, adupe
Eledumare, eku ise ooo
Adupe, adupe … adupe
Eku ise baba, eku ise ooo
Adupe … adupe
Eku ise ooo

 

 

 

 

 

Top