Arugbo Ojo – David G

 

SOLO

Mo wole fun o
Alagbada ina baba mi oo
Mo wole fun o
Ogbe ‘nu wundia s’dodo

Mo wole fun o
Ato farati bi oke won ni
Mo wole fun o
Arugbo Ojo

Mo wole fun o
Baba awon tio ni baba
Mo wole fun o
Kabio omasi o baba mi

Mo wole fun o
Ogbe ‘nu wundia s’dodo baba o
Mo wole fun o
Arugbo Ojo

CHORUS

Mo wole fun o
Mo wole fun o
Mo wole fun o
Arugbo Ojo /4x

SOLO

Kabiosi o baba
Alagbada Ina nio oo baba
Arugbo ojo nio ooo baba
Baba awon tio ni baba
Emi mimo ma nio o baba
Mimo mimo ma nio o baba mi
Eru jeje nio oluwa oba
Arugbo ojo

Baba mi nio ooo baba
Eleda mi nio baba
Atorise nio oo baba mi
Ataye se nio oo baba
Atowo se ma nio oo baba
Oloju ina nio oo baba mi
Emi mimo nio ooo
Arugbo ojo

Arugbo ojo nio oo baba
Kinihun eya judah nio oo baba
Mo wole fun o
Arugbo ojo

CHORUS

Mo wole fun o
Mo wole fun o
Mo wole fun o
Arugbo Ojo /4x

Top