Asa Mi – Eunice Melody

 

 

LEAD

Iwo ni Asà mi
Iwo ni Odi MI
Iwo ni mogbekemile
Iwo ni baba mi

CHORUS

Iwo in Asà mi(iwo in Asà mi)
Iwo ni odi ni (Apata mi)
Iwo ni mogbekemi le(Jesu baba mi o)
Iwo ni baba mi

Iwo ni Asà mi(Iwo ni Asà)
Iwo ni odi mi(Iwo ni odi mi)
Iwo ni mogbekemile (Iwo ni apata mi o
Iwo ni baba mi

VERSE

When am in pain
I will call to you
Cos you are fortress
You are may help
There’s nothing you cannot do /2x

CHORUS

Iwo ni Asà mi (Iwo lolugbeniga)
Iwo ni odi mi(iwololugbenisoke)
Iwo ni mogbekemile (Iwo ni mofemi mi le ooo)
Iwo ni baba mi

VERSE

Onikinmaberu, kinmafoyamo /2x
Ojo olami ohun bo wa dara
Iwo ni Olorun mi
Iwo ni adurotini /2x

CHORUS

Iwo ni Asà mi (Jesu ni Asà mi)
Iwo ni odi mi (baba lasa mi)
Iwo ni mogbekemile
(I have putting my trust in you…. o

Iwo ni Asà mi (Baba mi oo)
Iwo ni odi mi(Iwo ni odi)
Iwo ni mogbekemile (apata mi…..o)
Iwo ni baba mi

BRIDGE

I serve a God,
In him I have a brighter future
So trust in him, then he will bring the best out of you
My lord God, you are my Asà, odi and my Apata
Obatikijani kule

Top