Gbojule – Sola Allyson

 

Intro

Mo ma ri ore
Mo ma ri ore to po
Oro ti o ni’ye /2x

Amin ooo, aase
Amin ooo, aase
Amin ooo

Chorus

Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba fe’hin ti

Bee naa lari
Bee naa aase
Se bi awa ri Baba gbojule

Verse 1

Sometime ago, living in the darkness
Ireti do pin ooo
Ko maa s’enikan a saba o
Ife ti o l’akawe, lo wa mi ri
O tan imole so na mi
Ogbe mi s’ejika wale
Iyanu yen si wa, o si maa wa
Tori, awa ri Baba gbojule

Chorus

Se bi awa ri Baba gbojule, odeju saka
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba fe’hin ti

Bee naa lari
Bee naa aase
Se bi awa ri Baba gbojule

Verse 2

But, right now
My path is bright gan ni
Ife to se iyen wa
Sibe, kop le yi pada l’aye oo
Emi o l’ayo ninu re
Alasepe oore
Ole se ju bee lo, olododo ni Baba
Olutoju mis si wa, yio si maa be
Emi ma ri baba gbojule

Chorus

Se bi awa ri Baba gbojule, daju daju
Se bi awa ri Baba gbojule
Awa ma ri Baba gbojule ooo, kii d’oju tini o
Se bi awa ri Baba gbojule
Se bi awa ri Baba fe’hin ti

Bee naa lari
Bee naa aase
Se bi awa ri Baba gbojule

Outro

Bi eru wa, sibe o wa ko le yi pada lai lai
Se bi awa ri Baba gbojule
Alaanu, Olupese, Oludande, Oloore ni
Se bi awa ri Baba gbojule
Mo ri ore oro to po
Ileri re aase mo mi laara
Se bi awa ri Baba gbojule
Mo gbekele, mo mo asee, o ti so be
Oro re kii ye, ohun ni Baba
Se bi awa ri Baba gbojule

Top