Iba – Sola Allyson

Intro

Ibare ni maa faye miju
Sisin oo lemi a figba mise
Shebi iyen nooni Iyen gangan sha lo da mi fun
Eni ayeraye to nigba mi oo Ogo foo ko re

Chorus

Afuye gege tio she gbe
Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiyesio mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo /2x

Verse 1

Mo seba Re o, mo seba re
Mofori bale mo gbowo soke
Mo seba Re o, mo seba re
Nirele okan mo wa ri
Kabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo /2x

Talo leso ta lo le ka won
Awon irawo towa loju orun
Egbe isiro lewon ke so fun wa
Awon erupe inu okun
Talo le so talo moye
Ewa iseda toyi wa ka
Iyanu fun dudu iyanu fun funfun
Ose fe ni to gbon ateni to go
Kabiyesi o mo se ba re o
Oba to ju gbogbo oba lo

Repeat chorus

Verse 2

Oju mi tiri eti mi ti gbo
Iyanu re yi aye ka
Mogbo ninu eri awon eniyan mimo
Mori ninu itan emi gangan nitan
Gbogbo ise re dadada ni
Aburu kankan o todo re wa
Ohun gbogbo lole yi pada
Sugbon rara tododo re ko
Kabiyesi o moseba re oo
Oba toju gbogbo oba lo ee

Chorus

Afuye gege mama se gbe
(Okan mi pongbe mimoo si)
Emi wao mo n wa o si oo
Oba toju gbogbo oba lo ogo re yi aye ka
Emi seba mo sebaoo, mofori bale niwaju ite aanu
Oba agbanilagbatan
Oba adani magbagbe eni
Mo wa riiiiii
Emi seba re oo oh oh oh

Oba to ju gbogbo oba lo
(Oba to ju gbogbo oba lo)
Oba toju gbogbpo oba lo sara Re re ooo
(Ehn kayie sio mose bare o)
Emi yio ma fibukun fun o lojojumo iwo nikan loni ii
Ni gbogbo igba ni gbogbo asiko
Okan mi yio ma fogo fooko re

Oluwa orun ohun aye
Ewa re yi aye ka
Anfogo fooko re
Mojewo mojewo re
Iwonikan loluwa koselomiran leyin re
You are beautiful beyond description
Ewa re koja ogbon ori
You are wonderful beyond comprehension
Iyanu re koja oye

Top