Iyin – Sola Allyson

 

Eni baa mo nu ro lo le m’ope da
Eni baa ni arojinle asa ma dupe
Emi m’onuro mo ya wa dupe
Olorun ti ako le da duro
Mo gbe o ga ooo
Olorun ti ako le da duro
Mo gbe o ga ooo

Chorus

Olorun ti ako le da duro
Mo gbe o ga ooo /2x

Olorun ti a ko le mu lowo dani
Mo gbe o ga ooo
T’oba lo ya, ta lo le da o duro
Eto inu re lo wa, eto owo re lo wa
Mo gbe o ga ooo

Olorun ti ako le da duro
Mo gbe o ga ooo /2x

Kabiyesi, kabiyesi re Baba agba
Kabiyesi, kabiyesi re Oba awon oba
Kabiyesi, kabiyesi re Baba agba
Kabiyesi, kabiyesi re Oba awon oba

Kabiyesi re o Baba agba
Oba to joko lori ite o, ma sola re lo oluwa
Kabiyesi, kabiyesi re Baba agba
Kabiyesi, kabiyesi re Oba awon oba

Ofi imole s’aso bora
Oba to fi imole s’aso bora
Ori obiri aye lo joko si, imole lo fi s’aso bora
Oba to fi imole s’aso bora

Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora

Kabiyesi re oluwa
Emi mi bu ola fun o nigba gbogbo oba mi
Ni gbogbo aye ko s’eni to dabi ire oluwa
Iwo to joko si inu awon orun oluwa

Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora
Ofi imole s’aso bora

Oluwa, mogbe o ga ooo
Oluwa, mogbe o ga ooo
Awon orun bami yin o o, wipe ose
Awon orun bami yin o o, pe ose /2x

Oluwa, mogbe o ga ooo
Oluwa, mogbe o ga ooo
Gbogbo ise re n bami yin o oo, wipe ose
Mo daun mi po mo gbogbo ise re mo sobe o seun
Oluwa, mogbe o ga ooo
Oluwa, mogbe o ga ooo
Awon orun bami yin o o, wipe ose
Awon orun bami yin o o, pe ose

Ayin o oba mimo
Ayin o oloore wa
Ayin o olugbala
Iwo lo s’agbara wa /2x

Ayin o oba mimo
Ebo ope re e o
Lati ogbon okan wa wa ni
Wa gba oluwa olorun

Ayin o oba mimo
Ayin o oloore wa
Ayin o olugbala
Iwo lo s’agbara wa

Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa fiyin fun
Olorun mi to n gbe ni bi gi ga
Iwo ni mo wa gbe ga /2x

Iwo ni mo wa gbe ga ooo
Oba to ro ‘jo aanu s’ori iseda mi oluwa
Olorun mi to n gbe ni bi gi ga
Iwo ni mo wa gbe ga

Iwo ni mo wa gbe ga
Iwo ni mo wa fiyin fun
Olorun mi to n gbe ni bi gi ga
Iwo ni mo wa gbe ga

Alpha, Omega
Alpha, Omega
Iwo ni mo fiyin fun o Baba
Iwo ni mo fiyin fun o Baba /2x

Oba to mo ibere, iwo ni Alpha
Oba to mo opin, iwo ni omega
Iwo ni mo fiyin fun o Baba
Iyin re oni tan lenu mi ti ti aye mi

Alpha, Omega
Alpha, Omega
Iwo ni mo fiyin fun o Baba
Iwo ni mo fiyin fun o Baba

Oloore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mo gbe o ga /2x

Oloore ofe
Eleru niyin
Unexplainable, indescribeable
Unsearchable, incredible
Mo gbe o ga

Oloore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mo gbe o ga

Iyin ye, Olorun wa
Oba to n gbo adura
Iyin ye, Olorun wa
Oba to n gbo adura /2x

Iyin ye o, Olorun wa
Oba to fi aanu n gba’dua
Bio ba se wo to wa leyin mi
Ni bo le mi o bawa n bati b’aye lo
Oba to n gbo adura

Iyin ye, Olorun wa
Oba to n gbo adura
Iyin ye, Olorun wa
Oba to n gbo adura

Oti n se ise re bo
Iwo yio se lase pe
Oti n se ise re bo laye wa
Iwo yio se lase pe /2x

Oti n f’aanu gba mi bo oluwa
Iwo yio gba mi tan ooo, agbani lagba tan nio ooo
Oti n f’aanu yo mi bo, oba to mu mi de bi
Iwo yio se lase pe

Oti n se ise re bo
Iwo yio se lase pe
Oti n se ise re bo laye wa
Iwo yio se lase pe

Gb’adura mi go ke Baba
Gb’adura mi go ke
Oba afese jin
Oba afese jin
Oba afese jin
Gb’adura mi go ke /2x

Top