Logan Ti O De – TY Bello Ft Tope Alabi

Verse

Emi mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo
Mo mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo

Chorus

Logan to gbo iro ayo re o
Olugbala aye mi leto /2x

Verse

Mo mo’un aye ma tiwi
Mo mo’un eniyan ma tiso
Won ti pe wa ni agan ri
Bo ya won ti pe o lo’loshi ri

Chorus

Sugbon logan to de o
Olugbala l’aye mi leto
Sugbon logan to de yi o
Olugbala l’aye e leto

Verse

Aye to ti daru tele tele oo
Logan ti o de
Oro ti eniyan ti n fi alufani re
Logan ti o de
Oro ti ko dara ti a ti so si o
Logan ti o de

Oruko ti kin se ti e ta ti pe o
Logan ti o de
Ani logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti o de o
Olugbala, aye e leto

Chorus

Logan ti jesu de
Olugbala, l’aye e leto

Verse

Ko si oruko ti aye o le peni
Won a ma peni l’agan lona gbogbo
Bo ba lowo l’owo, agan ni
Bo ba bimo o, agan ni

Bo ba t’egbe ko d’agba, agan loje
Sugbon logan ti o de
Sope logan ti o de

Ani logan ti o de lesekese
Logan ti o de
Logan ti o de o
Olugbala, laye e leto

Logan ti o de
Logan ti o de
Eni ta pe l’agan e ma so pe
Logan ti o de
Awon ta ti f’oruko aburu pe nile won yi
Logan ti o de

Ani logan ti o de o
Olugbala, aye mi leto
Logan ti o de o
Olugbala, laye mi e leto

Ani logan ti o de o
Aseda, laye mi leto
Ani logan ti o de o
Olorun o, laye mi leto

Irawo owuro, omo mary yo s’inu oro mi
Laye mi leto
Alagbara ni shilo
Lo ba ranti mi si rere
Laye mi leto

Enu mi wa kun fun erin oo gbogbo
Aye mi leto
Aye mi gba iyipada otun logan to de
Aye mi leto

Aye mi ba le to l’ota ba n wo iran mi
Aye mi le to
Aye mi ba le to l’ota ba n wo iran mi
Aye mi le to

Ota ka wo ro
Enu won gbetan lori ojukan
Aye mi le to
Logan ti o de o
Olugbala, laye mi leto

Thank you Lord Jesus for all that You have done!

Top