Motiri (I’ve Seen) – Kenny Kore

Motiri – Kenny Kore

INTRO
Motiri ibiti
Eru ngbe rin bi oba
Ti o le marin bi ijoye
Tori ade ole da nkan ‘re se

I’ve seen…

Motiri ibiti
Eru ngbe rin bi oba
Ti o le nrin bi ijoye
Tori ade ole da nkan ‘re se

VERSE 1
Ile aye ti mo wa
Afowoba fi’le ni
You see I’m the best and the superstar
Afowoba fi’le ni

Molowo
Molowo
Molowo
Afowoba fi’le ni

Mofe digba
Mofe digba
Mofe digba
Awon to laye lana da?
Won ti ku wan ti lo

Moti ri ooo…

REPEAT [CHORUS]

VERSE 2
Kirakita o dola
No… Ko dola
Maa fi owuro mi se rere
Ko jo ale mi le ye mi

Kirakita o dola
No… Ko dola
Igbagbo ninu jesu
Ki doju tini

REPEAT [CHORUS]

Awon to laye lana da?
Won tiku won ti lo
Eri awon da?
Won tiku won ti lo
So gbo awon da?
Won ti fade away

Awon to laye lana da?
Won ti sako lo
Eri awon da?
Won ti paro lo

So gbo awon da?
Won ti repete lo
Eeee… awon da?
Won ti fade away

Invalid download ID.

…Enriching your world with music

Top
Share This