Oba Iyanu – Tosinbee

 

 

Alagbara toju ara oo
Alagbara toju ara lo
Oba iyanu, Onise iyanu
Oloruko iyanu
Ogbe ogo kari ogo
Losinu Ogo, Jesu

Ologo didan
Oba aiku
Oba ai sha
Oba ai di baje
Commander in chief
Mimo ninu awon orun

Okele kabiti
Okele kabiti
Okele kabiti tin ka alaseju laya
Aki ikitan eledumare

Asiwaju ogun lalo
Akeyin
Akeyin ogun labo
Eleda, Aseda
Aweda, Ameda
Kinihun eya Judah
Obirkiti ajipojo iku da

Unchangeable
Dependable
Reliable, Immunable
Unquestionable, Incomparable
Awogba arun magbeje
Awogba arun ma gbeje

See also: Tim Godfrey ‘Iyanu A Sele’, Sonnie Badu ‘Afrikan Medley’
Tosinbee ‘Soromidayo’, Calledout ‘Oba Ti De‘, Chingtok Ishaku ‘Ubangiji Na’

Alaafin ajobo
Alagbala adewure
Aarani banise
Oranmo nise faya ti
Olowogbogboro
Atobi tan, Adara tan
Ato fi se ognun ran

Gbangba gbangba
Kabiti kabiti
Janran janran
Fenfe fenfe
F’ola s’ade
F’ogo s’ola
F’ina s’aso ibo’ra

Olowo ina
Oloju ina
Alagbada ina
Owo kembe rebi’ja
Wongiri mogiri
Wongiri mogiri

Olagiri ka ka
Olagiri ka ka
Olagiri ka ka ka ka
Olagiri ka ka ka ka ka
ka ka ka ka ka
ka ka ka ka ka

To the greatest
To the Lord of lords
Hallelujah, hallelujah

 

Top