Olorun Iyanu – Teni Belega

 

 

CHORUS

Olorun iyanu ni
Oloruko aperire olorun iyanu ni
Oloriki egbaagbeje olorun iyanu ni

VERSE

Oloruko aperire eh olorun ododo,
ile iso agbara maloruko re o Olorun ododo,
Oruko tiku gbo to sa tarun gbo o to wole lo,akaikatan
Loruko re Olorun iyanu, Olorun owu,
Olorun ife oh Olorun Awon olorun kekeke,
Ayinyaintan Loruko re Olorun iyanu

BRIDGE

Baba ologojulo, ologodidan,
Emi yo ma yin o oh olumoran
Okan eda ah ah ah olorun pipe ni o

Top