Oriki – Tim Godfrey ft Xtreme

 

VERSE

Kabiyesi atoperi Eledumare mi se
Kabiyesi agba nla atoperi Eledumare mi
Baba mi awimayehun
Baba mi awilese OH

Baba mi aselewi
Baba mi ogbagba nla ti ngbani
Gbani Gbani lojo isoro
Eleti gbohun gbaroye

Abetilukara bi ajere
Eru jeje leti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni
Ota somo bi eni taso

Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai…

VERSE

Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Iba akoda
Iba aseda
Iba aweda

Iba ameda
Ogbagba tiri gbagba
Alagbada ina
Alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin

Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun
Moti fiyin feni tiyin nse tire o…

VERSE

Eni to n se mimo
To n je mimo
To n mu mimo
To n gbe bi mimo

To niwa mimo
Alade ogo
Talaba fi o we
Na you bi ano
Na you bi oni

Na u tuni lola
Ope ye o o Baba
Edumare gbope wa…

Tire ni o /7x

Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa

SWAP 1

Tire ni o/7x

SWAP 2

Tire ni o/7x

CALL & RESP

My praise
Belongs to you

Ese
Adupe o

Igwe /6x
Nna naba me
Igwe

Top